Nigerian Praise

Here are the lyrics. Clap your hands and sing along… WORSHIP… That's what we were created for!

Iba Re by SOLA Allyson (lyrics)

Posted on | July 29, 2019 | No Comments

Iba re ni ma f’aiye mi ju
Si’sin o l’emi a f’igba m’ise
S’ebi iyen na ni
Iyen gangan sa lo da mi fun
Eni aiye r’aye to ni’gba mi o
Ogo f’oko re

Chorus
Afuye gege ti o se gbe
Jigbini jigbini bi ate ileke
Kabiyesi o mo se’ba re
Oba to ju gbogbo oba lo
(2x)

Mo se’ba re o, mo se’ba re
Mo fori ba’le mo gbowo soke

Mo se’ba re o, mo se’ba re
Nirele okan mi mo wa ri

Kabiyesi o mo se’ba re
Oba to ju gbogbo oba lo

Emi se’ba re o, mo se’ba re
Mo fori ba’le mo gbowo soke
Mo se’ba re o, mo se’ba re
Nirele okan mi mo wa ri

Kabiesi o mo se’ba re
Oba to ju gbogbo oba lo

Ta lo le so
Ta lo le ka won
Awon irawo t’owa loju orun

Egbe isiro le won
Ke so fun wa
Awon erupe inu okun

Tal’o le so
Ta lo mo’ye
Ewa iseda t’oyi wa ka

Iyanu fun dudu
Iyanu fun fufun
Ose fe ni to gbon at’eni to go

Kaabiesi o mo se ba re o
Oba to ju gbogbo oba lo

Chorus
Afuye gege ti o se gbe
Jigbini jigbini bi ate ileke
Kabiyesi o mo se’ba re
Oba to ju gbogbo oba lo

Mo se’ba re o, mo se’ba re
Mo fori ba’le mo gbowo soke
Mo se’ba re o, mo se’ba re
Nirele okan mi mo wa ri

Kabiesi o mo se’ba re
Oba to ju gbogbo oba lo

Gbogbo aye gb’ohun soke ninu ewa won,
Won f’ogo fo’oko re

Ohun gbogbo fiyin fun o
Iwo nikan l’oba to’logo

Oju mi tiri
Eti mi ti gbo
Iyanu re yi aye ka

Mo gbo ninu eri awon eniyan mimo
Mori ninu itan
Emi gangan nitan

Gbogbo ise re da da da ni
Aburu kankan o t’odo re wa
Ohun gbogbo lo’le yi pada
Sugbon rara t’ododo re ko

Kabiyesi o mo se’ba re o
Oba t’oju gbogbo oba lo e

Chorus
Afuye gege ti o se gbe
Jigbini jigbini bi ate ileke
Kabiyesi o mo se’ba re
Oba to ju gbogbo oba lo

Mo se’ba re o, mo se’ba re
Mo fori ba’le mo gbowo soke
Mo se’ba re o, mo se’ba re
Nirele okan mi mo wa ri

Kabiyesi o mo se’ba re o
Oba t’oju gbogbo oba lo e
Oba toju gbogbo oba lo (4x)

Ogo re yi aye ka
Emi se’ba, mo se’ba o
Mo fori ba’le ni waju ite aanu
Oba agbanilagbatan
Oba adani magbagbe eni
Mo wa ri

Emi se’ba re o oh oh oh

Oba to ju gbogbo oba lo
Oba to ju gbogbo oba lo

Oba to ju gbogbo oba lo sara re re o
Oba to ju gbogbo oba lo

En kabiyesi mo se ba re o
Oba to ju gbogbo oba lo

Emi yi o ma fi bukun fun o lojojumo iwo nikan loni i
Oba to ju gbogbo oba lo

Ni gbogbo igba, ni gbogbo asiko, okan mi yio ma f’ogo f’okore
Oba to ju gbogbo oba lo

Oluwa orun ohun aiye ewa re yi aye ka, a n f’ogo f’okore hmm
Oba to ju gbogbo oba lo

Mo jewo mo jewo re, iwo nikan l’oluwa ko s’elomiran leyin re
Oba to ju gbogbo oba lo

You are beautiful beyond description, ewa re koja ogbon ori
Oba to ju gbogbo oba lo

Comments

Leave a Reply





  • Christian Film on Youtube Watch Now

    12 YEARS AND A DAY ........ (Short Film) ... .............. Official Trailer Below

  • Inspirational Fiction

    Tasha's World Crumbles but she refuses to stay down.....

  • Story of unexpected redemption

    A Thought Provoking Story of Redemption

  • Recent Posts

  • Tags

  • Recent Comments

  • Categories

  • Archives

  • Statcounter